Full Lyrics
[CHORUS]
Kí lo yẹ f'Ọlọrun
Ogo f'Ọlọrun
Ogo lo yẹ o Baba
[VERSE 1]
Ogo fun Ọlọrun l'ọrun o
Alafia f'awọn eniyan rẹ laye
Oluwa Ọlọrun ọrun
Ọba Ọlọrun ọrun ogo yẹ fun Ọba
[VERSE 2]
A yin o
A f'ọpẹ fun o
A wa fori wa balẹ yẹ fun Ọba
[VERSE 3]
Jesu Kristi Ọmọ bibi Baba
Iwọ t'o ko ẹṣẹ aye lọ
Wa ṣaanu fun wa Jesu
Ọba Ọlọrun ọrun ogo yẹ Baba
[VERSE 4]
Ẹni to joko l'ọwọ ọtun Baba
L'ọwọ ọtun Baba
Ṣaanu fun wa Ọba
Fun wa o Baba
[VERSE 5]
Ṣebi iwọ nikan ni mimọ
Iwọ nikan ni mimọ
Baba iwọ nikan l'Oluwa
Iye raye o
Ọba Ọlọrun ọrun ogo yẹ fun Ọba
[VERSE 6]
Iwọ Jesu Kristi
Ọmọ Baba
Pẹlu Ẹmi Mimọ o
Titi Baba
Ninu ogo Ọlọrun
Ọba rere
Amin aṣẹ ko ṣẹ
Amin ogo yẹ Baba