Full Lyrics
[INTRO]
Ogo ni f'Olorun loke orun,
Alaafia si ni laya f'awon eda oninu rere.
[VERSE 1]
Baba wa a gbe O ga
Afiyin a t'ola fun O
Ogo ye, Ogo ye f'Olorun wa.
Ogo ye, Ogo ye f'Olorun wa.
[CHORUS]
Ara e gbe e ga
Ope ye f'Olorun
Iyin ye f'Olorun
Ogo ye, Ogo ye f'Olorun wa
Ogo ye, Ogo ye f'Olorun wa
Amin.
[VERSE 2]
Oluwa Olorun wa
Odo Aguntan Olorun
Iwo to nko ese aye lo
Saa nu fun wa gbo ti wa
[VERSE 3]
Iwo nikan l'eni mimo
Oluwa to ga julo
Jesu Omo Baba
Ninu isokan Emi mimo