Full Lyrics
EGBE
Ogo f'Ọlọrun l'oke, ogo
F'Ọlọrun l'oke, ogo
Ogo f'Ọlọrun l'oke, ogo
Ogo f'Ọlọrun l'oke
Ogo f'Ọlọrun l'oke
Ogo, ogo f'Ọlọrun l'oke.
VERSE 1
Ogo ni f'Ọlọrun l'oke
Ogo! Ogo f'Ọlọrun l'oke
Awa yin Ọ
A fi bukun fun Ọ
A n f'oriba le fun Ọ
A nyin Ọ l'ogo
A f'ọpẹ fun Ọ ninu ogo nla Rẹ
Ogo! Ogo f'Ọlọrun l'oke.
VERSE 2
Oluwa, Ọlọrun, Ọba ọrun, Ọlọrun, Baba Olodumare
Oluwa Jesu Kristi, Ọmọ Rẹ kan ṣoṣo, ogo f'Ọlọrun l'oke.
VERSE 3
Ọdọ Aguntan Ọlọrun, Ọmọ ti Baba
Iwọ ẹni t'onko ẹṣẹ aye lọ, ṣa anu fun wa
Iwọ ẹni t'onko ẹṣẹ aye lọ, gbọ adura wa
Iwọ t'o joko l'ọwọ ọtun Baba, ṣa anu fun wa.
VERSE 4
Nitori Iwọ nikan ni mimọ
Iwọ nikan l'Oluwa, ogo f'Ọlọrun l'oke
Iwọ Jesu Kristi l'o ga ju l'ogo Ọlọrun Baba
Pẹlu Ẹmimimọ ninu ogo Ọlọrun Baba.