Full Lyrics
INTROSOLO
Ogo ni f'Ọlọrun loke ọrun
Alaafia si ni laye f'awọn ẹda oninurere
CHORUS
Baba wa a gbe ọ ga
A f'iyin ati ọla fun ọ
Ogo yẹ f'Ọlọrun wa
Ogo yẹ f'Ọlọrun wa
Ara ẹ gbe e ga
Ọpẹ yẹ f'Ọlọrun
Iyin yẹ f'Ọlọrun
Iyin yẹ f'Ọlọrun
Ogo yẹ f'Ọlọrun wa
Ogo yẹ f'Ọlọrun wa
Ogo yẹ f'Ọlọrun wa, Amin
Ogo yẹ f'Ọlọrun wa, Amin
VERSE 1
Oluwa Ọlọrun wa
Ọdọ Aguntan Ọlọrun
Iwọ to nko ẹṣẹ aye lọ
Ṣaanu fun wa gbọ ti wa
VERSE 2
Iwọ nikan l'ẹni mimọ
Oluwa to ga julọ Jesu
Ọmọ Baba
Jesu Ọmọ Baba
Ninu isọkan Ẹmi mimọ