AWA YIN O O... A FOGO FUN O BABA. [GLORIA IN YORUBA] by Oluwafemi Mathias O — Lyrics

Oluwafemi Mathias O Yoruba Gloria Solfa notation

Full Lyrics

CHORUS Awa yin Ọ o, a f'ogo fun Ọ Baba, Ọpẹ ni fun Ọ, a fori balẹ o, Awa yin Ọ o, a f'ogo fun Ọ Baba, Ọpẹ ni fun Ọ, a fori balẹ. VERSE 1 Ogo f'Ọlọrun l'oke, Alaafia l'aye f'awọn oninu rere, Ọla yẹ fun Ọ, ogo yẹ fun Ọ, Nitori ogo nla rẹ, Ọba Ọrun. VERSE 2 Oluwa, Ọlọrun wa o, Ọdọ Agutan to nko ẹṣẹ aye lọ, Ṣaanu fun wa, gbọ adura wa, L'atoke wa o, lọwọ ọtun Baba. VERSE 3 Iwọ, Jesu Kristi, Iwọ nikan ma ni, Mimọ o, Ninu ogo Ọlọrun to gaju lọ, Pẹlu Ẹmi Mimọ o, Ogo Mẹta l'ọkan.

Download the sheet music

AWA YIN O O... A FOGO FUN O BABA. [GLORIA IN YORUBA]

AWA YIN O O... A FOGO FUN O BABA. [GLORIA IN YORUBA]

By Oluwafemi Mathias O
Solfa
Yoruba
1 page
11 Downloads
Gloria
0 0

More lyrics you may want