Full Lyrics
INTRO
Ogo ni f'Olorun loke orun.
Alaafia si ni laya f'awon eda oninu rere.
VERSE 1
Baba wa a gbe O ga
A f'iyin a t'ola fun O
CHORUS
Ogo ye f'Olorun wa
Ogo ye f'Olorun wa
Ara e gbe e ga
Ope ye f'Olorun
Iyin ye f'Olorun
Ogo ye f'Olorun wa
Ogo ye f'Olorun wa
Amin
VERSE 2
Oluwa Olorun wa
Odo Aguntan Olorun
Iwo to nko ese aye lo
Saanu fun wa gbo ti wa
VERSE 3
Iwo nikan l'eni mimo
Oluwa to ga julo
Jesu Omo Baba
Ninu isokan Emi mimo