ADUPE - Choir Script PDF Thumbnail
Preview
0 0
1 downloads
Added Jul 31, 2026
Uploaded By: Choir PDFs
Format: Solfa
Language: Yoruba
Pages: 2 pages

ADUPE by Chaninomi A.-E. Joseph — Lyrics

INTRO A dúpẹ́ fún ohun tí ẹ ṣe fún wa Ore rẹ nínú ayé wa ó máa pọ̀ Olùfẹ́ ṣe, ẹ ṣe Olùgbàlà A dúpẹ́ o REFRAIN Gbọ́pé wa Bàbá Gbọ́ pé wa o Yìn àt'ògo ló yẹ ó o Bàbá Fún ore rẹ o o A dúpẹ́ o Bàbá UNISON Àwa la ti dúpẹ́ ìyànu rẹ Lórí wa, ẹ ṣe Bàbá a dúpẹ́ o Ọba wa ẹ ṣe Ọba wa Ló ti wa, ẹ ṣe o Bàbá o a dúpẹ́ o Ọba ẹ ṣe o Ọba wa VERSE 1 Gbogbo iye tí a ní láyé Bàbá láti ọ̀dọ̀ rẹ ló ti wá
Read full lyrics

About ADUPE

"Adupe" is a joyful Yoruba song of thanksgiving that rings out with gratitude for God's endless blessings. From its opening lines, the choir lifts up a collective voice of appreciation, acknowledging that every good thing in life comes from the Father. The melody is bright and rhythmic, making it a natural fit for the Thanksgiving procession when the congregation dances forward to present their gifts and tithes.

The arrangement by Chaninomi A.-E Joseph builds beautifully from a full-choir introduction into a lively refrain. In the verses, the lyrics praise God under many powerful titles—calling Him Kabiyesi (the Supreme King), Eledumare (the Creator), and the one who provides for today and tomorrow. The interplay between the cantor's calls and the choir's steady ostinato responses in the final verse creates a vibrant, layered sound that encourages everyone in the pews to join in the spirit of gratitude.