Full Lyrics
[Verse 1]
Adupẹ o Baba
Jesu, Baba, Jesu
Keresimesi ti de o
Oluwa o, Ah
Idunnu si ti kun aye
Ayọ kun o
Ayọ ni l'ọrun ayọ ni l'aye
Jesu, Olugbala
Olugbala Kristi de o
A ti ri irawo ogo
A na juba fun o Jesu
A bi Jesu, Imanueli
[Verse 2]
Awọn Angeli n kọrin Ayọ
Keresimesi ti de o
Adupẹ o Baba o
Ọba ti de, Olugbala ti de
Alade ogo ti de Ẹ kọrin Aleluya
Olugbala ti de k'a juba fun Ọba
Ọba ti de, Ọba awọn Ọba Jesu
Alade ogo ti de Ẹ kọrin Aleluya
Ẹ kọrin Aleluya
Ọba awọn Ọba Jesu Kristi
Olugbala na ti de
[Verse 3]
Olugbala wa ti de
Ẹmi mimọ nti ran wo a ran wa
Pa ra ram pa ra ram pa ra ram
Olugbala wa kaabọ o o
Ẹ ṣe o Ẹmi mimọ
Olugbala na ti de
Iranwọ lo gbe wa de
A gbogbo ninu Mesaya
Olugbala wa ti de
[Verse 4]
Adari gbogbo ẹda
Ni Bẹtẹlẹhẹmu ilu ti
Olugbala wa kaabọ o o
Ẹ ṣe o Ẹmi mimọ
Olugbala gi o
Ibukun ni fun Mariya t'o bi Ọba igbala
Olugbala wa ti de
A ti ri irawo rẹ o
Olugbala wa ti de
Olugbala wa kaabọ
O ṣe o Ẹmi mimọ
[Verse 5]
O si ndan yanan
Ni bugbe ẹranla
Olugbala wa kaabọ
Ẹ ṣe o Ẹmi mimọ
Ọba ni!
Olugbala wa ti de
Olugbala wa kaabọ
Olugbala wa kaabọ o o
Ẹ ṣe o Ẹmi mimọ
Olugbala wa kaabọ
Ọba ni! Ọba ni! Ọba ni!