Full Lyrics
VERSE 1
Oyin ni Jesu mo mọ yi dada Oyin l'Oluwa,
Mo mọ yi tori aye mi dara.
VERSE 2
Oyin adun ni Baba gbe wa Oyin 'yebiye,
T'ẹni to ba wa l'o Jesu yi wo.
VERSE 3
Oyin ni Jesu mo le wi f'aye Oyin l'Oluwa,
T'ẹni to ba fẹ gba Jesu yi o.
VERSE 4
Oyin adunyọ ni Baba ṣe wa Oyin 'yebiye,
A mọ yi tori a ni Oluwa.
INTRO
Oyin ni Jesu,
Oyin ni Jesu,
Oyin ni Jesu,
Oyin ni l'Oluwa.
CODA
Oyin mọmọ, Oyin l'Olu.
REFRAIN
Adun yoyo l'Ọlọrun wa,
O ba tọ wo k'o ri ire,
Wa mọ mọ yi dada,
Pe Oyin l'Oluwa.
Oyin, Oyin,
Oyin l'Oluwa.