Full Lyrics
[Chorus]
Jésù mi, iwókú lórí àgbélébùú nitori èsé mi,
sibè, ese mi n mu o je 'rora.
Nitori ifékùfé ara mo n súbú sinú èsè nigbà gbogbo.
Ah! Ijebi nlá ni!
Mo káàánú fún gbogbo irorare, Olúwa.
Mo káàánú fún gbogbo àisedédé.
Mo bèbè fún ooreòfé re, kin lè hùwà rere.
Opò igbà ni mo ti pinu láti fi àwon èsè mi silè.
Opò igbà ni mo n subú pada sinú èsè kan náà.
Ah! Olorun, nigbàkúùgbà ti mo bá d'ésè
ni mo n pàdá nù ooreòfé re
ijebi èsè ti dè mi mólè!
Oluwa, njé iwo yóò je ki n sègbé sinú èsè,
[Section C]
Mo kàáà nitori kò si Olùrànwó fún mi?
Ani ninú òpò ooreòfé re?
Ah! Jesu mi!
[Tenor Solo]
Nipa ijiyà re lóri Agbélébùú
Nipa irora ti o faradà
Nipa ikú re lóri Agbélébùú
Nipa iségun re lóri ikú
Nipa iségun re lóri èsè
Nipa iségun re lóri iná àinipeèkun
Mo jéwó wipé tire ni mo jé iwójé tèmi.
Ah! Olúwa!
[Chorus]
Ah! Mo kaaanu fun gbogbo ese mi.