Full Lyrics
Oni l'ojo pe Edumare,
Olupilese Oba mimo, O seun.
A wa dupe Olu Onon, a wa de,
Iwo l'Ojo, koni sojuwa o, a wa dupe.
Baba Onon a wa de, a dupe,
O se Baba Onon o, a dupe.
Jesu Oluwa, a wa dupe, a yin O lorun.
Eni to da wa si doni,
A wa dupe, a wa dupe, a yin Baba.
K'orin Alleluya, e yin Omo Igbala o,
Edumare, Ah, Alleluya ye o.
K'orin Alleluya si Baba Edumare.
Gbogbo eyin eniyan, e wa ba wa dupe,
A n ni Olukun Ola o.
A a ni, a a ni,
Ade ori wa ko si danun o, eyi de ti wa.