Full Lyrics
Oni lọjọ pe Edumare,
Oni lọjọ pe lọjọ ko o Edumare, Olupese.
Ọba Mimọ O seun,
Olugbala ọpẹ yẹ o O seun.
Awa dupẹ Olu ọrun, awa de,
ade o Baba, awa juba rẹ,
Iwọ lo jẹ koni soju wa o awa dupẹ,
Baba ọrun awa de, adupẹ Jesu,
adupẹ Baba, O ṣe Baba ọrun o.
Adupẹ o, adupẹ o, adupẹ o Jesu, Oluwa seun.
Adupẹ seun.
Awa dupẹ ayin Ọlọrun, awa de o,
awa dupẹ ayin Baba logo.
Ẹni toda wa si doni o,
awa dupẹ awa dupẹ, ayin Baba.
Kọrin alleluya ẹyin ọmọ igbala o,
kọrin alleluya si Baba Edumare, duma,
Adupẹ o, adupẹ o, adupẹ o Jesu, Oluwa seun.
Adupẹ seun.
Gbogbo ẹyin eniyan ẹwa bawa dupẹ,
A n ni ọla kun ọla, a n ni iyi kun iyi,
Ade ori wa ko si danu, eyi na ton ti wa.
Adupẹ o, adupẹ o, adupẹ o Jesu, Oluwa seun.
Adupẹ seun.