Full Lyrics
FEMALE SOLO INTRO
Ogo O, ogo O, ogo, Allelu, Alleluya, Alleluya O!
CHORUS
Ogo, ogo, Allelu, Alleluya,
Ogo, ogo, Allelu, Alleluya,
Ogo, ogo, Allelu, Alleluya,
f'Olorun l'oke orun.
Ogo ni f'Olorun loke orun,
Alafia f'aye f'awon eniyan re,
Ogo ni f'Olorun l'oke orun.
VERSE A
Awa yin O, awa fi'bukun fun O,
Awa yin O l'ogo Olu Orun O,
Asupe nitori ogo nla re,
Olorun loke Orun.
VERSE B
Oluwa Olorun Oba Orun,
Oluwa Olorun Omo bibi kan soso,
Oluwa Jesu Kristi Omo Olorun,
Olorun kan soso.
VERSE C
Oluwa Olorun Odo Agutan,
Omo ti Baba ti kese aye lo,
Jowo sare wa sanu fun wa,
Nitori ese wa.
VERSE D
Iwo eni to nko ese aye lo,
fi iye gbo ebe awa ra wa,
Iwo to wa lowo otun Baba,
Jowo sanu fun wa.
VERSE E
Iwo nikan ni Mimo,
Iwo nikan ni Oga julo,
Pel'Emi Mimo e ba n'ise,
Ninu ogo Olorun.