Full Lyrics
Ẹ ṣe o ẹ ṣe o, baba mi o ẹ ṣe, Ọlọrun ẹ ṣe
Baba mo dupẹ, dupẹ
Ọba Ọba Ọba nla
Ọba nla ẹ ṣe o baba, baba mi o baba, Ọbanla
O! Kabiyesi, Ọba nla, Ọlọrun baba
A dupẹ, Ọba Ọba Ọba nla
Ọlọrun baba, a dupẹ
Ẹ ṣe baba, a dupẹ iwọ l'Ọba iye gbọ rẹ
Ọba Ọba Ọba nla, Ọlọrun baba
A dupẹ iwọ l'Ọba iye, Ọba i ba
Oluwa Jesu Aah! Baba baba a dupẹ