Oba Ogo! - Choir Script PDF Thumbnail
Preview
0 0
5 downloads
Added Sep 28, 2025
Composer: Alex Ugwu (OZIGE)
Uploaded By: Choir PDFs
Format: Staff & Solfa
Language: Yoruba
Pages: 11 pages

Oba Ogo! by Alex Ugwu (OZIGE) — Lyrics

INTRO Ogo! Ọba awọn'ba, Ọlọrun rere, Ọba ogo gb'ọpẹ wa. O fun mi ni orin; Ogo! CHORUS O! Ẹ yin Oluwa l'ogo! Ẹ yin Oluwa l'ogo! Ẹ yin Oluwa l'ogo! Ẹ yin Oluwa l'ogo! Ọba idariji, Ọba giga, A dupẹ o Baba, Awa n yin o l'ogo. Aiye o. VERSE 1 Ni igbati nkan da, Oluwa wa pẹlu mi. Ni igbati gbogbo nkan le, Oluwa wa pẹlu mi. O fun mi ni orin ti mo le kọ, Ti ma lulu fun, ti ma jo si! Oluwa wa pẹlu mi. Oluwa wa pẹlu mi.
Read full lyrics

About Oba Ogo!

"Oba Ogo!" is a vibrant Yoruba anthem of praise that calls the choir and congregation to lift their voices to the King of Glory. Alex Ugwu’s composition is built on a foundation of deep gratitude, capturing the essence of a heart that chooses to praise God in every season. The lyrics beautifully declare that whether times are good or difficult, the Lord remains present, giving us a reason to sing, drum, and dance.

In the choir loft, this piece shines brightest during the Offertory or as a joyful Recessional. The second verse is especially moving, as it rolls through the mighty, traditional titles of God—calling Him Oyigiyigi (the great and mighty), Awimayehun (He who speaks and does not change His words), and Eledumare (God Almighty). As the tempo drives forward, the overlapping harmonies build an atmosphere of absolute celebration, making it a favorite for feast days and thanksgiving Masses.