Full Lyrics Mimọ, mimọ, mimọ, Mimọ l'Oluwa. VERSE 1 Ọrun ati aye kun fun ogo rẹ. REFRAIN Hosanna, Hosanna loke ọrun, Hosanna loke ọrun. VERSE 2 Ibukun ni f'ẹni t'on bọ wa L'orukọ Oluwa.