Full Lyrics
Mimo Mimo l'Oluwa
Mimo Eledumaare
Mimo Atofarati
Mimo iwo l'Oba ti ko yi pada
Mimo Oluwa awon oba
Mimo Orun oun aiye yin o o
Mimo Hosana loke orun
Hosana loke orun
Mimo Ibukun ni f'eni t'on bo wa
Mimo l'oruko Olorun o
Mimo Hosana loke orun
Hosana loke orun
Mimo Mimo Mimo