Korin Si Baba by Ademola Adeosun — Lyrics

Ademola Adeosun Yoruba Offertory Hymns FILM Songs FILM 2023 Celebrations Hymns Solfa notation

Full Lyrics

[VERSE 1] Baba gbọpẹ, wa gbọpẹ Baba gbọpẹ wa, Orin iyin Lanko si ọ, Baba gbọpẹ wa; Orin Ọpẹ Lanko si ọ, Baba gbọpẹ wa; Orin ayọ Lanko si ọ, Baba gbọpẹ wa; gbọpẹ, gbọpẹ gbọpẹ na o, [REFRAIN] Baba gbọpẹ wa; Kọrin, Kọrin, Kọrin si Baba, fi iwa ti o jọ si gbọpẹ ranga [VERSE 2] Awọn eso ile aye, Wọn jẹ Ore Rẹ, Ẹ bun Rẹ ni awọn Ohun Ọgbọn ala woo wura, O n fi imọ lẹ ati O kun kun ran ṣe, Ẹ jẹ ka jumọ yin in pẹlu Orin Ọpẹ [CANTOR] T'ẹlẹwa ni ilẹ ati ẹkun rẹ, Ẹ jẹ ka jumọ yin in pẹlu Orin Ọpẹ [FEMALE VOICE (SOPRANO)] Ni toriti O ti Ṣe ipilẹ Rẹ, Si inu omi, Kọ dupe [ALL CANTORS] Ẹ jẹ ka jumọ yin in pẹlu Orin Ọpẹ [MALE VOICE (TENOR)] O si fi idi rẹ kalẹ, Lori odo [ALL CANTORS] Ẹ jẹ ka jumọ yin in pẹlu Orin Ọpẹ [UNISON] a wa yin o Kọ Orin iyin wa; Kọrin, kọrin Rẹ kikankikan Baba gbọpẹ wa Baba gbọpẹ wa Baba gbọpẹ wa Baba gbọpẹ wa Baba gbọpẹ wa a dun idupẹ a la dun ni a mu wa; a dun idupẹ a la dun ni a mu wa; a dun idupẹ a la dun ni a mu wa; [UNISON] Baba gbọpẹ wa

Download the sheet music

Korin Si Baba

Korin Si Baba

By Ademola Adeosun
Solfa
Yoruba
3 pages
6 Downloads
Offertory Hymns FILM Songs FILM 2023 Celebrations Hymns
0 0

More lyrics you may want