Ka Ju'ba F'Ọba - Choir Script PDF Thumbnail
Preview
1 0
7 downloads
Added Sep 29, 2025

Ka Ju'ba F'Ọba by Ademola Adeosun — Lyrics

[Adagio] Ọba wa t'o de, Olugbala t'o de o, Ara ẹ yọ... [Baritone Solo] Ẹ f'ope f'Ọba awa yoo fi gbogbo ọkan wa yin O. [Vivace] A yọ ninu Rẹ Je k'a lọ f'iba fun Olugbala t'o wa lati wa gbawa la, Oṣuba f'Ọba, Ọba Ologo julọ, Iba Rẹ re o. [Soprano Solo] Ka f'iba f'Ọba o, Iba o, Ka polongo ẹ faraiye Oluwapada araiye Ọba oke ati ilẹ O wa lati gba wa l'ọwọ iku Oun l'Olurapada araiye Iba f'Ọlu ọrun Iba f'Ọba mimọ [Chorus] Iba, iba, Iba o, iba, iba Iba, iba, Iba o, iba, iba Iba, iba, Iba o, iba, iba
Read full lyrics

About Ka Ju'ba F'Ọba

"Ka Ju'ba F'Ọba" is a vibrant Yoruba anthem of praise that calls the congregation to pay homage to the Almighty King. From its opening adagio, which announces the arrival of the Savior, the piece quickly transitions into a lively, rhythmic celebration of God's majesty. The lyrics invite everyone to rejoice and declare the greatness of the Redeemer who saves us from death.

Choirs often bring this piece to life during the Entrance procession, the Offertory, or as a joyful Recessional. The arrangement features dynamic interplay between the full choir and expressive solo parts, building up to a powerful climax of adoration. Singing "Ọba o, Ọba o, a juba fun Ọ o" (King, O King, we pay homage to You), the voices unite in a profound expression of reverence and gratitude that resonates deeply within the church.