Full Lyrics
CHORUS
Gbẹbọ wa, dakun Baba Mimọ O,
Gbẹbọ wa, Olodumare, Olodumare,
Gbẹbọ wa dakun Baba O,
Gbẹbọ wa, Olodumare,
Baba O, gbẹbọ wa,
Ẹbọ! Mimọ! Ẹbọ! Pipe!
Ẹbọ mimọ, Ẹbọ pipe,
Ye, dakun! Ẹbọ mimọ, Ẹbọ pipe,
Ẹbọ! Iye O, Ẹbọ! Iye O,
Bi iye ba ra si O,
Ẹbọ mimọ, Ẹbọ pipe,
Ẹbọ iye, Ẹbọ iye ba ra si O.
Gbẹbọ O, Baba O, gbẹbọ wa,
Baba O, gbẹbọ wa, Baba wa O.
VERSE 1
Akara l'a mu wa,
Oti l'a mu wa,
Wa lati inu ẹsọ t'o fun wa,
Jọwọ ma sai gbẹbọ wa,
Baba dakun gbẹbọ wa,
Baba O, gbẹbọ wa.
VERSE 2
Olodumare, Oluwa, jọrẹ,
Jọwọ wa gbẹbọ wa,
Jọwọ wa gbẹbọ wa.
Olodumare, Baba Olore, Ye dakun,
Jọwọ wa gbẹrẹ wa O,
Jọwọ wa gbẹbọ wa O.
Olodumare.