GBA AWỌN ẸBUN WA, BABA WA ONIIFẸ TITI LAI by MICHAEL CHIEDOZIE UZOMAH — Lyrics

MICHAEL CHIEDOZIE UZOMAH Yoruba FILM Songs FILM 2023 Offertory Hymns Hymns Staff & Solfa notation

Full Lyrics

PRELUDE Ọlọrun Alagbara, awa ọmọ rẹ wa nibii pẹlu ẹbun Mini ọpọ ohun to Ẹ fun wọn. Lati dupẹ lọwọ Yin Ọba awọn ọba Olupẹse nla. CHORUS Fun awọn ohun ti Ẹ fun wa riri ati airi Awa lati dupẹ lọwọ Yin. Baba wa oniifẹẹ titi lai. Awa pẹlu ẹbun ninu ọpọ awọn ohun ti ẹ se lati dupẹ lọwọ Yin Baba wa oniifẹẹ titi lai. VERSE 1 Fun ẹbun ẹmi, fun ẹbun ara pipe, fun Adupẹ Olupẹse nla Olupẹse nla Olupẹse nla Baba wa oniifẹẹ titi lai. Ti ko ba ṣe ti Yin, ati ifẹ ti Ẹ ni si wa, Nibo lawa ọba wa? Kini awa ọ ba mi? Olupẹse nla Baba wa oniifẹẹ titi lai. VERSE 2 Titi lai ni emi O yin ọ Ọba mi ati Ọlọrun mi Ẹ mu mi de ibi ipa eniyan ko le mu mi de Ẹ pe mi ni ti Yin ati pe Ẹ pese fun mi, gẹgẹ bi ọrọ Yin ninu Ogo Kini idi ti mi O ṣe ni dupẹ? VERSE 3 Gba ẹbun wa Baba wa oniifẹẹ titi lai. Gba ẹbun wa Baba wa oniifẹẹ titi lai. Ẹti ibukun fun mi ni gbogbo ọna pẹlu aiye to dara, pẹlu ọru Pẹlu ile alafia ati ayọ, pẹlu ara pipe Gba ẹbun wa Baba wa oniifẹẹ titi lai. gba ọrẹ ọpẹ iyi Lati inu ọpọ Gba ẹbun wa Baba wa oniifẹẹ titi lai. Atiwa siwaju Yin Ọlọrun pẹlu ọpẹ fun ibukun Yin Ti atẹyin wa, ati lọwọlọwọ Gba ẹbun wa Baba wa oniifẹẹ titi lai. ọpọ ibukun ni akoko ti onbọ Amin Gba ẹbun wa Baba wa oniifẹẹ titi lai.

Download the sheet music

GBA AWỌN ẸBUN WA, BABA WA ONIIFẸ TITI LAI

GBA AWỌN ẸBUN WA, BABA WA ONIIFẸ TITI LAI

By MICHAEL CHIEDOZIE UZOM...
Staff & Solfa
Yoruba
48 pages
25 Downloads
FILM Songs FILM 2023 Offertory Hymns Hymns
3 0

More lyrics you may want