ELU AGOGO KERESIMESI by Jude Nwankwo — Lyrics

Jude Nwankwo Yoruba Christmas Hymns Solfa notation

Full Lyrics

Elu agogo, elu agogo, elu agogo. Elu agogo. Elu agogo, elu agogo Keresimesi, elu agogo. Elu agogo, Olugbala de o, elu agogo. Elu soke, Elu agogo, elu agogo, elu agogo Keresimesi, elu agogo. Elu agogo, Olugbala de o, elu agogo. Elu soke. Àwọn 'lùṣọ́ aguntan, wọn sọ ẹran wọn, Imọlẹ yi wọn ka, wọn ni "ki lode o?" Aṣe Olugbala labi Olugbala wa, Kabọ. Elu soke, Elu agogo, elu agogo, elu soke, elu agogo, elu agogo Keresimesi, elu agogo. Elu agogo Olugbala de o, elu agogo. Irawọ kan yọ loju ọrun. Irawọ, Irawọ. Àwọn angẹli nkorin loke O p'Olugbala wa ti de, Olugbala wa Kabọ. A fọpẹ fun Baba, A fọpẹ fun Ọmọ, A fọpẹ fun Ẹmi Mimọ o. Ẹmi Mimọ p'Olugbala wa ti de, Olugbala wa Kabọ. Elu agogo, elu agogo, elu agogo, elu agogo, elu agogo, elu agogo, elu agogo. Elu agogo. Elu soke, Elu agogo, elu agogo, elu agogo Keresimesi, elu agogo, Elu agogo Olugbala de o, elu agogo. Kabọ Jesu, Kabọ. Elu agogo, elu agogo Olugbala de o. Elu agogo. Elu agogo Olugbala de o, Elu agogo. Elu agogo Keresimesi. Elu agogo Keresimesi.

Download the sheet music

ELU AGOGO KERESIMESI

ELU AGOGO KERESIMESI

By Jude Nwankwo
Solfa
Yoruba
3 pages
17 Downloads
Christmas Hymns
0 0

More lyrics you may want