Full Lyrics
[INTRO]
Uba omo a temi mimo ya pelu ra ubowo inn.
Dede, mimo Jesu. Dede Jesu o.
[CHORUS]
Dede ki in yin Olua ti tori e inn bo a ninu ogo.
Dede o, dede ko o moribale ko Jesu ti tori e i bo lo na inn,
Emi mimo, sa mona ra n'isokan,
pelu metalokan tori ate sunwaju ka ayo
ninu ayo umole Re.
Ayo, yo umole Re.
[VERSE 1]
Inn dede in in a we mi, Jesu inn li bi
pepe, in je a josin fun ujoba Re,
inn je a mu dupe ra koo, e sayo
ko ju ufe Jesu Kristi lo, tori e i,
eye ugbe kam ba i pe ki kete ra.
[VERSE 2]
Ufe re dun jo'yin ko dun lo,
mimo mimo mimo oore o
fere poju hun elo aye lo,
mimo mimo mimo o r'okan
ra, ore mi ra, eninu re
to a li kike p'oruko Re kikete raa.
[VERSE 3]
Oyi yoo yin la aye ra
inhan okuta ati inhan igi yoo
yin olanla re ninu aye ra, aju
bii gege lo oo Emi Ni
mimo ayo mimo
tori e i, i a ka je eda oore gbudo gba
kun hun ke elemi ke i gbupo i ake isuke
re, li kete ugbe, tori e i awe kikete raaa.