Full Lyrics
CHORUS
Gb'ọrẹ wa o, gb'ọrẹ wa o,
Eledumare a wa ṣe.
Fun ore ọfẹ rẹ ninu aiye wa,
Baba adupẹ o,
Gb'ọrẹ ti a mu wa Eledumare.
VERSE 1
Ọpẹ iyin ogo l'a mu wa
Si'waju rẹ Baba.
Ijo ilu a t'orin l'a mu wa
Si'waju rẹ Baba loke.
T'ẹwọ gb'ọpẹ wa,
T'ẹwọ gb'ọpẹ wa,
Baba loke,
Gb'ọrẹ ti a mu wa Eledumare.
VERSE 2
O ṣe fun wa o t'o pe,
Ninu ohun k'ohun k'a ma dupẹ:
Ohun ti ba ṣẹlẹ o si ṣe pọ fun rere fun wa.
Adupẹ, adupẹ, Baba adupẹ o,
Gb'ọrẹ ti a mu wa Eledumare.
VERSE 3
Mo mọ riri ore Baba o,
Sunmọ bi wa gbe, Baba ṣe rere fun wa.
Sunmọ bi wa gbe, Baba ṣe rere fun wa.
Sunmọ bi wa gbe, Baba ṣe rere fun wa.
Gb'ọ a mọ riri ore rẹ a wa dupẹ.