Gloria - Yoruba (Ara E Gbe E-Ga) by Jude Nnam — Lyrics

Jude Nnam Yoruba Gloria Mass Settings Solfa notation

Full Lyrics

[Intro] Ogo ni f'Ọlọrun loke ọrun. [Tutti] Alaafia si ni laye f'awọn ẹda aninu rere. Baba wa a gbe e ga. A yin ọ, a tọ ọ, a f'ogo fun ọ. [Chorus] Ara ẹ gbe e ga, ọpẹ yẹ f'Ọlọrun. Iyin yẹ f'Ọlọrun, ogo yẹ f'Ọlọrun wa. [Verse 1] Oluwa Ọlọrun wa, Aguntan f'Ọlọrun wa. Iwọ to nko ẹṣẹ aye lọ, Ṣaanu fun wa, gbọ ti wa. [Verse 2] Iwọ nikan l'ẹni mimọ, Iwọ to ga julọ. Jesu ọmọ Baba, Ninu isọkan Ẹmi Mimọ. Amin.

Download the sheet music

Gloria - Yoruba (Ara E Gbe E-Ga)

Gloria - Yoruba (Ara E Gbe E-Ga)

By Jude Nnam
Solfa
Yoruba
3 pages
3 Downloads
Gloria Mass Settings
0 0

More lyrics you may want