Full Lyrics
[Intro]
Ogo ni f'Ọlọrun loke ọrun
Alaafia si ni laya fun wọn ẹda Ọlọrun rere
[Choir]
A gbe Ọ ga
Afiyin a t'ọla fun Ọ
Ogo yẹ f'Ọlọrun wa
[Chorus]
Ara ẹ gbe e ga
Ọpẹ yẹ f'Ọlọrun
Iyin yẹ f'Ọlọrun
Ogo yẹ f'Ọlọrun wa
Ogo yẹ f'Ọlọrun wa
[Verse]
Oluwa Ọlọrun wa
Ọdọ Aguntan Ọlọrun
Iwọ to nko ẹsẹ aye lọ
Ṣaanu fun wa gbọ ti wa
Iwọ nikan l'ẹni mimọ
Oluwa to ga julọ
Jesu Ọmọ Baba
Ninu isọkan Ẹmi mimọ