Ara E Dide by Lyte C. Onyema — Lyrics

Lyte C. Onyema Yoruba Entrance songs Celebrations Solfa notation

Full Lyrics

REFRAIN Ara ẹ dide ẹ ba mi jo, eniyan mi ẹ ba mi yọ. Oluwa mi lo gbe mi ga. VERSE 1 Ninu ohun gbogbo O pa mi mọ, ninu ewu gbogbo o mu mi ye. Ki lo tun yẹ mi bi ko ṣe ọpẹ, ọpẹ ni temi l'ọjọ gbogbo. VERSE 2 O wa f'ire gbogbo da mi l'ọla, O tun f'ohun rere t'o tun ga ju. T'o m'aye yẹ mi t'o m'ọrun yẹ mi, B'o ṣe ayọ mi l'ọjọ gbogbo. VERSE 3 O tun f'ọmọ rere da mi l'ọla, O mu mi j'ọba sinu ayọ. Mo dupẹ mo dupẹ baba o ṣe, ẹ ba mi yọ, mo dupẹ jọjọ.

Download the sheet music

Ara E Dide

Ara E Dide

By Lyte C. Onyema
Solfa
Yoruba
1 page
15 Downloads
Entrance songs Celebrations
0 0

More lyrics you may want