Full Lyrics
[CHORUS]
A dupẹ fun ohun ti ẹ ṣe fun wa,
Ọrẹ rẹ ninu aye wa o ma pọ, Olupese, ẹ ṣe Olugbala.
A dupẹ o, gbọ'pẹ wa Baba, gbọ'pẹ wa o.
Iyin at'ogo lo yẹ o o Baba, fun ọrẹ rẹ o.
A wa lati dupẹ iyanu rẹ lori wa, ẹ ṣe.
Baba, a dupẹ o Ọba wa. Ẹ ṣe.
Baba, a dupẹ o Ọba wa.
[VERSE 1]
Gbogbo iye ti a ni l'aye Baba,
Lati ọdọ rẹ lo ti wa Ọba mimọ,
Ọba oke, Olu ọrun olubukun,
Olutọju a gbe ọ ga.
Gbogbo iye ti a ni l'aye Baba,
Lati ọdọ rẹ lo ti wa Ọba mimọ,
Ọba oke, Olu ọrun olubukun,
Olutọju a gbe ọ ga.
[TENOR SOLO & CHOIR]
Awa ọmọ araye a wa dupẹ ọrẹ ana,
A dupẹ ọrẹ oni, a tun dupẹ ọrẹ ọla.
Ẹ ṣe, ẹ ṣe, ẹ ṣe,
Gbọ'pẹ Baba, gbọ'pẹ Ọmọ,
Gbọ'pẹ Ẹmi mimọ, gbọ'pẹ Baba.
Alade ogo a dupẹ ọrẹ rẹ.
[TENOR CANTOR & CHOIR]
Kabiyesi, Baba, Eledumare o Ọba a wa dupẹ ọrẹ,
Kabiyesi, Baba, Eledumare o Ọba a wa dupẹ ọrẹ,
Kabiyesi, Baba, Eledumare o Ọba a wa dupẹ ọrẹ,
Kabiyesi, Baba, Eledumare o Ọba a wa dupẹ ọrẹ,
Olugbeja, Ọba to to, Ẹlẹda wa o Ọba a wa dupẹ ọrẹ,
Kabiyesi, Baba, Eledumare o Ọba a wa dupẹ ọrẹ,
Olupese, Ọba pipe, Awimayẹhun o Ọba a wa dupẹ ọrẹ,
Kabiyesi, Baba, Eledumare o Ọba a wa dupẹ ọrẹ,
Olugbala, Ọba aye, Atofara ti o Ọba a wa dupẹ ọrẹ,
Kabiyesi, Baba, Eledumare o Ọba a wa dupẹ ọrẹ,
A wa dupẹ ọrẹ, a wa dupẹ ọrẹ,
A wa dupẹ ọrẹ, rẹ a wa dupẹ ọrẹ,
Kabiyesi, Baba, Eledumare o Ọba a wa dupẹ ọrẹ.