Full Lyrics
INTRO
Olugbala lode, Olugbala kaabo
Oluwosan lode, Oluwosan kaabo
JOYFULLY
Ab' Olugbala abi o
Ab' Olugbala abi o
CHORUS
Ab' Olugbala abi o
Ab' Olugbala f'omo araye
O wa lati se'tusile abi
O wa lati mu wa kuro l'oko eru o
Abi Jesu Olugbala abi o
VERSE 1
Omo Maria abi
Omo Josefu abi
Omo lorun oga ogo ni
O wa lati da wa nide o
O wa lati fi'gbala fun wa
Olodumare a yin o o
VERSE 2
A bi Oluwa l'oru
Ab'Oluwa n'ibujeran
Ko wa gba wa la laye
Ko wa segun fun wa o
Ko wa se tu si le wa
Lowo iku oun ese o
VERSE 3
E je k'ajo kadupe ayo ara
Igbala pipe ti de fun wa
E je k'ayo ayo ti de
Ayo abara tintin
Iwosan pipe ma lo de o
Olutunu wole de fun wa o ye
Olorun loke o ma seun
CODA
Idande, iwosan o
Idande, idande
Idande, igbala o
O wa lati se dande abi
O wa lati se'tusile ati bi
O wa lati mu wa kuro l'oko eru o
O wa lati wosan fun wa
O wa lati munu wa dun laye
O wa lati fun wa niye o
Ab'olugbala, ab'olugbala
Ab'olugbala o!