ABI OLUGBALA NI IBUJE ERON - Choir Script PDF Thumbnail
Preview
0 0
1 downloads
Added Jul 31, 2026
Composer: SIKADEJOH JOHN
Uploaded By: Choir PDFs
Format: Solfa
Language: Yoruba
Pages: 2 pages

ABI OLUGBALA NI IBUJE ERON by SIKADEJOH JOHN — Lyrics

Baba ẹ ṣe p'ore Jesu Iyin ọpẹ fun Baba Ẹ lu ago tai tai Goke tari resimesi A bi Jesu abo titi Mẹta juba fun Jesu Wọle fun 'su Kristi Maria bi Oluwa gbala ire Ti de fun wa Ẹ lu ago ago ago ago ago yọ ayọ A bi Olugbala Ni ibuje ẹron Ilu Bethlehem Awọn angẹli wọn Kọrin Hosanna Alleluya Ẹ wa wo ọmọ tuntun o Maria bi fun wa Ogo f'Ọlọrun loke ọrun Alafiya si ni laye F'awọn ẹda oninu re Iranwọ kan lo yọ soju ọrun
Read full lyrics

About ABI OLUGBALA NI IBUJE ERON

"Abi Olugbala Ni Ibuje Eron" is a vibrant Yoruba Christmas carol that brings the joy of the Nativity straight into the choir loft. The title translates to "The Savior is born in the manger," and the music captures the excitement of that holy night. From the very first lines, the song calls us to give thanks and praise for the gift of Jesus, ringing out with the festive, rhythmic sounds of bells ("Ẹ lu ago") and celebration.

As the piece unfolds, it paints a lively picture of the scene in Bethlehem. We hear the angels singing Hosanna and Alleluia, and the shepherds gathering to bow before the newborn King. The melody is bright and energetic, making it a perfect choice for a parish carol service or the joyful procession on Christmas morning. It invites the whole congregation to join the heavenly chorus, singing "Ogo f'Ọlọrun loke ọrun" (Glory to God in the highest) and welcoming the light that has come into the world.